Brymo – Adedotun Lyrics

2020-05-10 12:22:12 -0400

[Verse 1] Awon adan fo loke Wan foka si oju Orun Wan o ma mo ibi won lo Eledua lo n shey ike won Ko keyin si é Oré o O wun o n wa O wa ni waju re

[Hook] Adedotun……. Oyindamola mi……. Ero gbogbo e ba gberin Adedotun o………….

[Verse 2] Awon adan fo loke Ni igba igba Won ku oju orun Won o ma mo iwun wan n je Eledua lo n sho wan Lo n bo wan Ko pamo si é Oré ooooooo O wa lo sokoto O wa lapo Sokoto

[Hook] Adedotun……. Oyindamola mi……. Ero gbogbo e ba gberin Adedotun o…………. (X2)

Ko pamo si é Oré o Owun o n wa O wa ni waju re Ore o……..

«Newer      Older»
Comment:
Name:

Back to home

Subscribe | Register | Login | N